Nọ́ḿbà 2:20-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Ẹ̀yà Mánásè ni yóò tẹ̀lé wọn. Olórí Mánásè ni Gàmálíélì ọmọ Pedasúrì.

21. Iye ìpín rẹ̀ ni ẹgbàá mẹ́rìndínlógún-ó-lé-igba (32,200).

22. Ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ni yóò tẹ̀ lé e. Olórí Bẹ́ńjámínì ni Ábídánì ọmọ Gídíónì.

Nọ́ḿbà 2