Nọ́ḿbà 19:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí ni ohun tí òfin Olúwa pa láṣẹ béèrè lọ́wọ́ yín: Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọn mú ẹgbọrọ ọ̀dọ́ màlúù pupa tí kò lábùkù tàbí àbàwọ́n, tí kò sì tí ì ru ẹrù rí.

Nọ́ḿbà 19

Nọ́ḿbà 19:1-7