Nọ́ḿbà 16:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kejì gbogbo ìjọ ènìyàn kùn sí Mósè àti Árónì pé, “Ẹ ti pa àwọn ènìyàn Olúwa.”

Nọ́ḿbà 16

Nọ́ḿbà 16:39-46