Nọ́ḿbà 16:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwọn ènìyàn yìí bá kú bí gbogbo ènìyàn ti ń kú, bí ìrírí wọn kò bá sì yàtọ̀ sí ti àwọn ènìyàn yóòkù, a jẹ́ pé kì í ṣe Olúwa ló rán mi.

Nọ́ḿbà 16

Nọ́ḿbà 16:25-35