Nọ́ḿbà 15:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n mú un jáde sí ẹ̀yìn ibùdó, gbogbo ìjọ ènìyàn sì sọ ọ́ lókúta pa, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mósè.

Nọ́ḿbà 15

Nọ́ḿbà 15:35-39