Nọ́ḿbà 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí ẹ sì mú ọrẹ àfinásun wá, yálà nínú ọ̀wọ́ ẹran gẹ́gẹ́ bí òórùn dídùn sí Olúwa, bóyá ọrẹ sísun tàbí ẹbọ sísun, láti san ẹ̀jẹ́ pàtàkì tàbí ọrẹ àtinúwá,

Nọ́ḿbà 15

Nọ́ḿbà 15:1-11