Nọ́ḿbà 14:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí inú Olúwa bá dùn sí wa, yóò mú wa dé ilẹ̀ náà, ilẹ̀ tó ń ṣàn fún wàrà àti fún oyin, yóò fún wa ní ilẹ̀ náà.

Nọ́ḿbà 14

Nọ́ḿbà 14:1-10