Nọ́ḿbà 14:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ihà yìí ni ẹ ó kú sí, gbogbo ẹ̀yín tí ẹ kùn láti ọmọ ogún ọdún ó lé àní gbogbo ẹ̀yin tí a kà.

Nọ́ḿbà 14

Nọ́ḿbà 14:19-35