Nọ́ḿbà 13:4-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Orúkọ wọn nìwọ̀nyí:láti inú ẹ̀yà Rúbẹ́nì Ṣámuá ọmọ Ṣákúrì;

5. láti inú ẹ̀yà Símónì, Ṣáfátì ọmọ Hórì;

6. láti inú ẹ̀yà Júdà, Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè;

7. Láti inú ẹ̀yà Ísíkárì, Ígálì ọmọ Jósẹ́fù;

Nọ́ḿbà 13