Ó wí pé, “Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi:“Bí wòlíì Olúwa bá wà láàrin yínÈmi Olúwa a máa fara à mi hàn án ní ojúran,Èmi a máa bá a sọ̀rọ̀ nínú àlá.