Nọ́ḿbà 11:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósúà ọmọ Núnì tí í ṣe ìránṣẹ́ Mósè, láti kékeré tó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ dáhùn pé, “Mósè olúwa mi, dá wọn lẹ́kun!”

Nọ́ḿbà 11

Nọ́ḿbà 11:26-29