Nọ́ḿbà 10:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣe fèrè fàdákà méjì pẹ̀lú fàdákà lílù, kí o má a lò ó láti máa fi pe ìjọ ènìyàn àti láti máa fi darí ìrìnàjò lọ sí ibùdó yín.

Nọ́ḿbà 10

Nọ́ḿbà 10:1-5