Nọ́ḿbà 10:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ìpín ti ibùdó ti Rúbẹ́nì ló gbéra tẹ̀le wọn, lábẹ́ ọ̀págun wọn. Élísúrì ọmọ Sédúrì ni ọ̀gágun wọn.

Nọ́ḿbà 10

Nọ́ḿbà 10:11-28