Nọ́ḿbà 1:6-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Láti ọ̀dọ̀ Símónì, Ṣélúmíélì ọmọ Ṣúrísáddáì;

7. Láti ọ̀dọ̀ Júdà, Násónì ọmọ Ámínádàbù;

8. Láti ọ̀dọ̀ Íssákárì, Nítaníẹ́lì ọmọ Ṣúárì;

9. Láti ọ̀dọ̀ Ṣébúlúnì, Élíábù ọmọ Hélónì;

10. Láti ọ̀dọ̀ àwọn sọmọ Jósẹ́fù:láti ọ̀dọ̀ Éfraimù, Elisámà ọmọ Ámíhúdì;Láti ọ̀dọ̀ Mánásè, Gámáélì ọmọ Pedasúrù;

11. Láti ọ̀dọ̀ Bẹ́ńjámínì, Ábídánì ọmọ Gídíónì;

Nọ́ḿbà 1