Nọ́ḿbà 1:51 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbàkígbà tí àgọ́ yóò bá tẹ̀ṣíwájú, àwọn ọmọ Léfì ni yóò tu palẹ̀, nígbàkígbà tí a bá sì tún pa àgọ́, àwọn ọmọ Léfì náà ni yóò ṣe é. Ẹnikẹ́ni tó bá súnmọ́ tòsí ibẹ̀, pípa ni kí ẹ pa á

Nọ́ḿbà 1

Nọ́ḿbà 1:49-54