Nọ́ḿbà 1:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ọgbọ̀n ọ̀kẹ́-ó-lé-egbéjìdínlógún-dín-àádọ́ta, (603,550).

Nọ́ḿbà 1

Nọ́ḿbà 1:44-51