Nọ́ḿbà 1:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Dánì jẹ́ ẹgbàá mọ́kànlélọ́gbọ̀n-ó-lé-ẹẹ̀dẹ́gbẹ̀rin (62,700).

Nọ́ḿbà 1

Nọ́ḿbà 1:34-45