Nọ́ḿbà 1:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iye tí a kà nínú ẹ̀yà Éfúráímù jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì-ó-lé-ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (40,500).

Nọ́ḿbà 1

Nọ́ḿbà 1:26-43