Nọ́ḿbà 1:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìran Ísákárì:Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún sókè tí wọ́n le lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Nọ́ḿbà 1

Nọ́ḿbà 1:23-31