Nehemáyà 9:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ fi ẹ̀mí rere rẹ fún wọn láti kọ́ wọn. Ìwọ kò dá mánà rẹ dúró ní ẹnu wọn, ó sì fún wọn ní omi fún òrùngbẹ.

Nehemáyà 9

Nehemáyà 9:12-27