Nehemáyà 9:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kan náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì péjọ pọ̀, wọ́n gbààwẹ̀, wọ́n wọ aṣọ ọ̀fọ̀, wọ́n sì da eruku sórí ara wọn.

Nehemáyà 9

Nehemáyà 9:1-7