Nehemáyà 7:72 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àròpọ̀ gbogbo ohun tí àwọn ènìyàn tókù fi sílẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ méjì dírámásì wúrà, ẹgbẹ̀rùn-ún méjì mínà fàdákà àti ẹ̀tàdínláàdọ́rin ẹ̀wù fún àwọn àlùfáà.

Nehemáyà 7

Nehemáyà 7:5-73