Nehemáyà 6:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo dá èsì yìí padà sí i pé: “Kò sí ohun kan nínú irú ohun tí ìwọ sọ tí ó ṣẹlẹ̀; ìwọ kàn rò wọ́n ní orí ara rẹ ni.”

Nehemáyà 6

Nehemáyà 6:4-17