Nehemáyà 5:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi àti àwọn arákùnrin mi àti àwọn ènìyàn mi, pẹ̀lú ń yá àwọn ènìyàn lówó àti oúnjẹ (ọkà). Ṣùgbọ́n ẹ jẹ́ kí a dáwọ́ owó èlé gbígbà yìí dúró!

Nehemáyà 5

Nehemáyà 5:4-16