Nehemáyà 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí tí ó tún wà ní ẹ̀gbẹ́ wọn ni àwọn ọkùnrin Tẹ́kóà tún mọ, ṣùgbọ́n àwọn ọlọ́lá kò ṣe àtìlẹ́yìn fún iṣẹ́ náà lábẹ́ àwọn olórí wọn.

Nehemáyà 3

Nehemáyà 3:3-8