Nehemáyà 3:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àti àwọn ìránṣẹ́ẹ tẹ́ḿpìlì tí ó ń gbé ní òkè Ófélì ṣe àtúnṣe títí dé ibi ọ̀kánkán ibodè omi sí ìhà ìlà oòrùn àti ilé ìṣọ́ tí ó yọ sóde.

Nehemáyà 3

Nehemáyà 3:18-28