Nehemáyà 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnu ìbodè Ààtàn ni Málíkíjà ọmọ Rákábù, alákóṣo agbégbé Bẹti-Hákérémù tún mọ. Ó tún un mọ, ó sì gbé àwọn ìlẹ̀kùn rẹ̀, àwọn ìdábùú ìlẹ̀kùn àti àwọn ìde rẹ̀ sí ààyè wọn.

Nehemáyà 3

Nehemáyà 3:6-20