Nehemáyà 13:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé àwọn baba ńlá yín kòha ti ṣe nǹkan kan náà tí Ọlọ́run wa fi mú gbogbo àjálù yìí wá oríi wa, àti sórí ìlú yìí? Báyìí, ẹ̀yin tún ń ru ìbínú ṣókè síi sórí Ísírẹ́lì nípa bíba ọjọ́ ìsinmi jẹ́.”

Nehemáyà 13

Nehemáyà 13:16-19