Nehemáyà 13:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rántíì mi fún èyí, Ọlọ́run mi, kí o má sì ṣe gbàgbé ohun tí mo fi òtítọ́ ṣe fún ilé Ọlọ́run mi yìí àti fún iṣẹ́ ẹ rẹ̀ gbogbo.

Nehemáyà 13

Nehemáyà 13:10-16