Nehemáyà 12:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn olóórí ìdílé àwọn ọmọ Léfì ní ìgbà ayé Élíáṣíbù, Jóíádà, Jóhánánì àti Jádúà, àti pẹ̀lú ti àwọn àlùfáà ni a kọ sílẹ̀ ní ìgbà ìjọba Dáríúsì ará a Páṣíà.

Nehemáyà 12

Nehemáyà 12:12-24