Nehemáyà 12:16-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. ti ìdílé Ídò, Ṣekaráyà;ti ìdílé Gínétónì, Mésúlámù;

17. ti ìdílé Ábíjà, Ṣíkírì;ti ìdílé Míníámínì àti ti ìdílé Móádíà, Pílítaì;

18. ti ìdílé Bílígà, Ṣámúyà;ti ìdílé Ṣémáyà, Jéhónátanì;

Nehemáyà 12