Nehemáyà 12:1-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì tí ó bá Ṣérúbábélì ọmọ Ṣéálítíélì àti Jéṣúà padà:Ṣeraiáyà, Jeremáyà, Éṣírà,

2. Ámáríyà, Málúkì, Hátúsì,

3. Ṣekánáyà, Réhúmù, Mérémótì,

4. Ídò, Gínétónì, Ábíjà,

5. Míjámínì, Móádáyà, Bílígà,

6. Ṣémááyà, Jóíáríbù, Jédááyà,

Nehemáyà 12