Nehemáyà 11:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣánóà, Ádúlámù àti àwọn ìletò o wọn, ní Lákísì àti àwọn oko rẹ̀, àti ní Ásékà àti awọn ìletò rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń gbé láti Bíáṣébà títí dé àfonífojì Hínómì.

Nehemáyà 11

Nehemáyà 11:21-36