Nehemáyà 10:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gẹ́gẹ́ bí a sì ti kọ ọ́ sínú ìwé òfin, àwa yóò mú àkọ́bí àwọn ọmọkùnrin wa, ti ohun ọ̀sìn wa, ti àwọn abo màlúù àti ti àwọn àgùntàn wa, wá sí ilé Ọlọ́run wa, fún àwọn àlùfáà tí ń ṣiṣẹ́ níbẹ̀.

Nehemáyà 10

Nehemáyà 10:29-39