Nehemáyà 10:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“A ti ṣe ìlérí pé, a kò ní fi àwọn ọmọbìnrin wa fún àwọn tí wọ́n wà ní àyíkáa wa bí ìyàwó, tàbí fẹ́ àwọn ọmọbìnrin wọn fún àwọn ọmọkùnrin wa.

Nehemáyà 10

Nehemáyà 10:25-33