Náhúmù 3:18-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

18. Ìwọ ọba Ásíríà,àwọn olùṣọ àgùntàn rẹ̀ ń tòògbé;awọn ọlọ́lá rẹ yóò máa gbé inú ekuru.Rẹ àwọn ènìyàn rẹ fọ́nká lórí àwọn òkè ńlá,tí ẹnikẹni kò sì kó wọn jọ.

19. Kò sì sí ohun tí ó lè wo ọgbẹ́ ẹ rẹ sàn;ọgbẹ́ rẹ kun fún ìroraGbogbo ẹni tí ó bá sì gbọ́ ìròyìn rẹyóò pàtẹ́wọ́ lé ọ lórí,nítorí ni orí ta ni,ìwà buburu rẹ kò ti kọjá nígbà gbogbo?

Náhúmù 3