Náhúmù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Asà àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sì di pupa;àwọn ológun wọn sì wọ aṣọ òdòdó.Idẹ tí ó wà lórí kẹ̀kẹ́ ogun ń kọ mọ̀nàmọ̀nàní ọjọ́ tí a bá pèsè wọn sílẹ̀ tán;igi fìrì ni a ó sì mì tìtì.

Náhúmù 2

Náhúmù 2:1-13