Náhúmù 2:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Àwọn apanirun ti dìde sí ọ, ìwọ Nínéfèpa ilé-ìsọ́ mọ́,ṣọ́ ọ̀nà náàdi àmùrè, ẹ̀gbẹ́ rẹ kí ó le,múra gírí.

2. Olúwa yóò mú ọláńlá Jákọ́bù padà sípògẹ́gẹ́ bí ọláńlá Ísírẹ́lìbí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn apanirun ti pa ibẹ̀ run,tí wọ́n sì ti run àwọn àjàrà wọn.

Náhúmù 2