Náhúmù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni ó lé dúró níwájú ìbínú rẹ̀?Ta ni ó lé faradà gbígbóná ìbínú rẹ̀?Ìbínú rẹ̀ tú jáde bí iná;àwọn àpáta sì fọ́ túútúú níwájú rẹ̀.

Náhúmù 1

Náhúmù 1:1-12