Mátíù 9:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wí fún wọn pé, “Ẹ máa lọ; nítorí ọmọbìnrin náà kò kú, sísùn ni ó sùn.” Wọ́n sì fi i rín ẹ̀rín ẹlẹ́yà.

Mátíù 9

Mátíù 9:14-29