Mátíù 9:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣì kíyèsí i, obìnrin kan ti ó ní ìsun ẹ̀jẹ̀ ní ọdún méjìlá, ó wá lẹ̀yìn rẹ̀, ó fi ọwọ́ kan ìṣẹ́tí aṣọ rẹ̀.

Mátíù 9

Mátíù 9:18-22