Mátíù 3:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹ má sì ṣe rò nínú ara yin pé, ‘Àwa ní Ábúráhámù ní baba.’ Èmi wí fún yín, Ọlọ́run lè mu àwọn ọmọ jáde láti inú àwọn òkúta wọ̀nyí wá fún Ábúráhámù.

Mátíù 3

Mátíù 3:1-17