Mátíù 28:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn obìnrin náà sáré kúrò ní ibojì pẹ̀lú ìbẹ̀rù àti ayọ̀ ńlá. Wọ́n sáré láti sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn nípa ìróyìn tí ańgẹ́lì náà fi fún wọn.

Mátíù 28

Mátíù 28:1-11