Mátíù 27:56 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú àwọn obìnrin ti ó wà níbẹ̀ ni Màríà Magidalénì, àti Màríà ìyá Jákọ́bù àti Jósẹ́fù, àti ìyá àwọn ọmọ Sébédè méjèèjì wà níbẹ̀ pẹ̀lú.

Mátíù 27

Mátíù 27:51-59