Mátíù 26:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ti ń jẹun, obìnrin kan wá sọ́dọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ìgò òróró ìkunra iyebíye, ó sì dà á sí i lórí.

Mátíù 26

Mátíù 26:1-17