Mátíù 26:69 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lákòókò yìí, bí Pétérù ti ń jókòó ní ọgbà ìgbẹ́jọ́, ọmọbìnrin kan sì tọ̀ ọ́ wá, ó ní, “Ìwọ wà pẹ̀lú Jésù ti Gálílì.”

Mátíù 26

Mátíù 26:67-75