Mátíù 26:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù wí fún un pé, “Bí ó tilẹ̀ jẹ́ láti kú pẹ̀lú, èmi kò jẹ́ sẹ́ ọ.” Gẹ́gẹ́ bẹ́ẹ̀ ni gbogbo àwọn ọmọ-ẹ̀yìn wí.

Mátíù 26

Mátíù 26:34-38