Mátíù 26:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù sì dá a lóhùn pé, “Bí gbogbo ènìyàn tilẹ̀ kọ̀ ọ́ sílẹ̀, èmi kì yóò ṣe bẹ́ẹ̀.”

Mátíù 26

Mátíù 26:23-37