Mátíù 25:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo jẹ́ àlejò, ẹ̀yin kò tilẹ̀ gbà mi sílé. Mo wà ní ìhòòhò, ẹ̀yin kò fi aṣọ bò mi. Mo ṣàìsàn, mo sì wà lọ́gbà ẹ̀wọ̀n, ẹ̀yin kò bẹ̀ mí wò.’

Mátíù 25

Mátíù 25:33-46