Mátíù 25:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà náà ni yóò sọ fún àwọn tí ọwọ́ òsì pé, ‘Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi, ẹ̀yin ẹni ègún, sínú iná àìnípẹ̀kun tí a ti tọ́jú fún èṣù àti àwọn ańgẹ́lì rẹ̀.

Mátíù 25

Mátíù 25:40-43